Anelloviridae

Anellovirus
Ìṣètò ẹ̀ràn
Group:
Group II (ssDNA)
Ìdílé:
Anelloviridae
Genera

Alphatorquevirus
Betatorquevirus
Gammatorquevirus
Deltatorquevirus
Epsilontorquevirus
Etatorquevirus
Iotatorquevirus
Thetatorquevirus
Zetatorquevirus

Anelloviridae jẹ́ ẹbí àwọn àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn kan tí a ṣẹ̀ṣẹ̀ mọ́. Wọ́n kàwọ́n sí àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn tí ó légungun tí ó sì ní ẹ̀wù ìdáàbòbò tí o gbó dáradára, tí ó rí róbótó, tí igun rẹ̀ jọ ara wọn, pẹ̀lú ogún igun tó jọrawọn. Àwọn ẹ̀yà wọ̀n yí jẹ́ àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn ti torque teno  (ìdílé Alphatorquevirus).[1]

  1. "Torque Teno Virus (TTV) distribution in healthy Russian population". Virology Journal 6: 134. 2009. doi:10.1186/1743-422X-6-134. PMC 2745379. PMID 19735552. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=2745379. 

From Wikipedia, the free encyclopedia · View on Wikipedia

Developed by Tubidy