Chad Basin National Park

Chad Basin National Park(Èdè Yorùbá: ọ̀gbà ìṣeré Chad Basin), jé ọgbà ìṣeré kan ní apá àríwá ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, ní Chad Basin, pẹ̀lú ilẹ̀ tí ó tó 2,258 km2. Wọ́n pín ọgbà náà sí mẹ́ta. Apá Chingurmi-Duguma wà ní Ìpínlẹ̀ Bọ̀rnó, ní agbègbè Sudanian Savanna . Àwọn apá Bade-Nguru àti Bulatura wà ní Ìpínlẹ̀ Yòbè ní agbègbè Sahel.[1]

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named NNPS

From Wikipedia, the free encyclopedia · View on Wikipedia

Developed by Tubidy