Masīhuzzamān Khān | |
---|---|
2nd Chancellor of Darul Uloom Nadwatul Ulama | |
In office 20 July 1903 – 21 April 1905 | |
Asíwájú | Muhammad Ali Mungeri |
Arọ́pò | Khalīlur Raḥmān S |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1840 Shahjahanpur, Mughal India |
Aláìsí | 17 December 1910 Shahjahanpur, British India | (ọmọ ọdún 69–70)
Masīhuzzamān Khān (1840 – 17 December 1910) fìgbà kan jẹ́ onímọ̀ Mùsùlùmí ti orílẹ̀-èdè India, tó jẹ́ gíwá kejì fún ilé-ìwé Darul Uloom Nadwatul Ulama[1]. Òun ni olùkọ́ fún Mir Laiq Ali Khan àti Mahboob Ali Khan.